Ojú Kálé: Àwọn omọ Naijiria sọ̀rọ̀ sí Ọ̀rọ̀ Ọba Bìíní lórí Ìṣẹ̀dálẹ̀ Ìlú Èkó

Ojú Kálé: Àwọn omọ Naijiria sọ̀rọ̀ sí Ọ̀rọ̀ Ọba Bìíní lórí Ìṣẹ̀dálẹ̀ Ìlú Èkó


A bá àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ nípa ọ̀rọ̀ tí ọba Bìíní sọ ní kòpẹ́kòpẹ́ yìí wí pé àwọn babańlá àwọn ni wọ́n tẹ ìlú Èkó dó.

Ọ̀pọ̀ àwọn ọmọ Yorùbá ló ti fárígá lórí ẹ̀rọ ayélujára, nígbà tí àwọn mìíràn sì fi ìdí ọ̀rọ̀ náà múlẹ̀ wí pé òdodo ni.

All rights reserved. This material, and other digital content on this website, may not be reproduced, published, broadcast, rewritten or redistributed in whole or in part without prior express written permission from PUNCH.

Contact: [email protected]

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *